Leadership Development Working Group/ Community Call Invitation

From Meta, a Wikimedia project coordination wiki
This page is a translated version of the page Leadership Development Working Group/Community Call Invitation and the translation is 62% complete.
Outdated translations are marked like this.

TL;DR: akọsílẹ̀ oríkì tí ìgbìmọ̀ amúṣẹ́ṣe Adarí gbé kalẹ̀ ni ti fi léde fún àgbéyẹwò gbogbo àwùjọ láti ọjọ́ kaẹ̀ẹ́dógún oṣù kẹsàn an ọdún 2022. Ẹ lè wo feedback period títí di ojọ́ kẹfà oṣù kẹwá ọdún 2022. Ìkéde yí ni a fi ṣe ìkópa ìgbéyàwó oríkì náà tí yóò wáyé ní orí ẹ̀rọ ayélujára ní ọjọ́ Àbámẹ́ta ọjọ́ kejìdínlógún àti ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n, ọdún 2022. Jọ̀wọ́ forúkọ rẹ sílẹ̀ nísàlẹ̀ !

Ìkéde fún àwùjọ

Ìgbìmọ̀ amúṣẹ́ṣe àwọn Adarí LDWG ti fi akọsílẹ̀ nípa ohun tí a gbà wípé ó jẹ́ oríkì fún ìgbìmọ̀ wa, èyí wà fún ìgbéyẹ̀wò gbogbo àwùjọ láti ọjọ́ kaẹ̀ẹ́dógún oṣù kẹsàn an ọdún 2022. títí di ojọ́ kẹfà oṣù kẹwá ọdún 2022.

Ìbí ni on ti lè rí akọsílẹ̀ àwọn oríkì náà. O sì lè lo èyíkéyí ọ̀nà tí ó bá wù ọ́ láti fi jíròrò lórí ọ̀kan-ò-jọ̀kan èrò rẹ lórí wọn.

O sì lè wo àwọn oríkì náà fínífíní bí ó bá dọ́gba pẹ̀lú èrò àti ìrírí tìrẹ nípa àwùjọ Wmf. O sì tún le tọ́ka sí àwọn aléébù tí ó wà nínú àwọn akọsílẹ̀ tiwa nípa Adarí bí wọn kò bá kún tó. Ẹ̀wẹ̀, o sì tún lè wo oríkì yí wo bí ó bá bá ìwòye àṣà, èdè tàbí ohun míràn mu nínú àwùjọ rẹ, kí o s ì sọ fún wa.

Níparí gbogbo àgbéyẹwò, a ó ṣe agbékalẹ̀ ifọ̀rọ̀-jomitoro-ọ̀rọ̀ jákè-jádò agbáyé lórí bí a ṣe lè mú ìlọsíwájú bá àwọn oríkì náà nípa gbígbọ́ t'ẹnu gbogbo àwùjọ patá.

Ìjíròrò náà yóò gùn tó wákàtí kan gbáko tí a ó sì fi ogún ìṣẹ́jú ṣe ìfáarà sí ohun tí a fẹ́ sọ gangan, kí a tó bẹ̀rẹ̀ sí ń f'àyè gba onírúurú ìjíròrò láti ẹnu àwọn olùkópa gbogbo.

A ṣe ìjíròrò náà lórí Zoom. A ó sì fi ilà ìwọlé s'órí Zoom náà ṣ'ọwọ́ s'ójú Ewé yí tí ó bá ti ń ku ọjọ́ péréte sí ìpàdé náà. A kò ní gbohùn ẹnikẹ́ni síl, bákan náà ni kò pín dandan fún ẹnìkẹ́ni láti darapọ̀ lọ́ ìjíròrò náà pẹ̀lú fífdíò tàbí kí wọ́n pe wọlé. Gbogbo olùkópa lè lo akọsílẹ̀ ṣáàtì láti fi da sí ọrọ̀ pẹ̀lú.

Ìjíròrò yí yóò wáyé ní èdè Gẹ̀ẹ́sì pẹ̀lú ògbufọ̀ ní èdè Spanish ati èdè Russia. A lè gba èdè méjì siwájú si nínú ìjíròrò kọ̀ọ̀kan. Jọ̀wọ́ bèèrè fún èdè rẹ kí ó lè wà nínú àwọn èdè àmúlò. Èdè tí wọ́n bá ti bèèrè fún ju ẹ̀marùn un lọ ni a ó gbà wọlé.

Agbékalẹ̀

Ìjíròrò Àwùjọ 1: Western Hemisphere friemdly

Add yourself

  1. --Rocío Mantis (talk) 21:03, 7 October 2022 (UTC)[reply]
  2. 787IYO (talk) 19:51, 8 October 2022 (UTC)[reply]
  3. Iwuala Lucy (talk) 18:21, 11 October 2022 (UTC)[reply]
  4. Guillotinado (talk) 18:25, 11 October 2022 (UTC)[reply]
  5. Danidamiobi (talk) 19:08, 11 October 2022 (UTC)[reply]
  6. NANöR (talk) 20:15, 11 October 2022 (UTC)[reply]
  7. Sarah Ab (talk) 20:15, 11 October 2022 (UTC)[reply]
  8. alhen Did you call? 13:26, 12 October 2022 (UTC)[reply]
  9. ShahajadaSJ7 (talk) 16:15, 12 October 2022 (UTC)[reply]
  10. Towhidul Islam 21 (talk) Towhidul Islam 21Towhidul Islam 21 (talk) 07:15, 13 October 2022 (UTC)[reply]
  11. Tahsin T. Talha (talk) 07:39, 13 October 2022 (UTC)[reply]
  12. Alphakitty (talk) 5:17, 12 October 2022 (UTC)
  13. Bijendra Hansda Purudhul (talk) 08:06, 14 October 2022 (UTC)[reply]
  14. Shabab Mustafa (talk) 16:31, 14 October 2022 (UTC)[reply]
  15. Bobbyshabangu (talk) 20:09, 14 October 2022(UTC)
  16. Ptinphusmia (talk) 13:37, 16 October 2022 (UTC)[reply]
  17. CSinha (WMF) (talk) 06:35, 17 October 2022 (UTC)[reply]
  18. ɴᴅᴀʜɪʀᴏ ᴅᴇʀʀɪᴄᴋ 🐎 (talk) 09:54, 17 October 2022 (UTC)[reply]
  19. Meenakshi nandhini (talk) 05:37, 18 October 2022 (UTC)[reply]
  20. Nada kareem22 (talk) 13:06, 20 October 2022 (UTC)[reply]
  21. Newtrains (talk) 14:41, 20 October 2022 (UTC)[reply]
  22. Inas.khateeb (talk)
  23. --ProtoplasmaKid (talk) 22:32, 20 October 2022 (UTC)[reply]
  24. Anna Torres (WMAR) (talk) 16:28, 21 October 2022 (UTC)[reply]
  25. Mtenaespinoza (talk) 18:12, 21 October 2022 (UTC)[reply]
  26. Galahad (sasageyo!)(esvoy) 01:40, 22 October 2022 (UTC)[reply]
  27. Onwuka Glory (talk) 18:07, 25 October 2022 (UTC
  28. --Ngoudechi (talk)
  29. Viva33 (talk) 21:49, 29 October 2022 (UTC)[reply]

Ìjíròrò Àwùjọ 2: Eastern Hemisphere friendly

Add yourself

  1. --LPiantá (WMB) (talk) 17:42, 5 October 2022 (UTC)[reply]
  2. --Olugold (talk) 13:54, 10 October 2022 (UTC)[reply]
  3. --Gilbert Ndihokubwayo (talk) 22:52, 10 October 2022 (UTC)[reply]
  4. --XenoF (talk) 14:24, 11 October 2022 (UTC)[reply]
  5. --Guillotinado (talk) 18:25, 11 October 2022 (UTC)[reply]
  6. --Senator Choko (talk) 20:10, 11 October 2022 (UTC)[reply]
  7. --Orabs1996 (talk) 20:47, 11 October 2022 (UTC)[reply]
  8. --Tiputini (talk) 07:56, 12 October 2022 (UTC)[reply]
  9. --ShahajadaSJ7 (talk) 16:16 , 12 October 2022 (UTC)
  10. -- कन्हाई प्रसाद चौरसिया (talk) 02:47, 13 October 2022 (UTC)[reply]
  11. -Sayant Mahato talk 06:36, 13 October 2022 (UTC)[reply]
  12. -- Towhidul Islam 21 (talk) 07:14, 13 October 2022 (UTC)Towhidul Islam 21Towhidul Islam 21 (talk) 07:14, 13 October 2022 (UTC)[reply]
  13. --Tahsin T. Talha (talk) 07:40, 13 October 2022 (UTC)[reply]
  14. --Alphakitty (talk) 5:18, 12 October 2022 (UTC)
  15. --Bijendra Hansda Purudhul (talk) 08:07, 14 October 2022 (UTC)[reply]
  16. --Danielly Campos Dias (talk) 15:05, 14 October 2022 (UTC)[reply]
  17. Rocky Masum (talk) 16:33, 14 October 2022 (UTC)[reply]
  18. CSinha (WMF) (talk) 06:36, 17 October 2022 (UTC)[reply]
  19. Meenakshi nandhini (talk) 05:31, 18 October 2022 (UTC)[reply]
  20. --Azogbonon (talk) 11:06, 19 October 2022 (UTC)[reply]
  21. --AAkhmedova (WMF) (talk) 19:19, 19 October 2022 (UTC)[reply]
  22. -- Contaminadas (talk) 13:17, 20 October 2022 (UTC)[reply]
  23. --ProtoplasmaKid (talk) 22:34, 20 October 2022 (UTC) I hope![reply]
  24. RamzyM (WMF) (talk) 15:10, 24 October 2022 (UTC)[reply]
  25. Lebron jay (talk) 15:21, 26 October 2022 (UTC)Lebron jay[reply]
  26. Semmy1960 (talk)
  27. ~~PassionateLibrarian(talk)
  28. Akwugo (talk) 19:40, 28 October 2022 (UTC)[reply]
  29. Sayvhior (talk) 09:05, 29 October 2022 (UTC)[reply]
  30. Agbalagba TC 08:11, 29 October 2022 (UTC)[reply]