Movement Strategy and Governance

From Meta, a Wikimedia project coordination wiki
This page is a translated version of the page Movement Strategy and Governance and the translation is 31% complete.
Outdated translations are marked like this.

Movement Strategy and Governance nṣe àtìlẹ́yìn fún ìkópa àwọn ará àjọṣepọ̀ àti ẹ̀ka Wikimedia nínú àwọn èrò Strategy Àjọṣepọ̀. A tún ma nṣe àtìlẹ́yìn fún àwọn ọ̀rọ̀ lórí ìlànà gbòógì àti ètò ìjọba, bíí àwọn òfin lílò, Àlàkalẹ̀ fún Ìhùwàsí tàbí ètò ìdìbò ìgbìmọ̀ onígbọ̀wọ́.

Ohun tí a jẹ́

Ẹgbẹ́ Movement Strategy and Governance jẹ́ ará ìpín Community Resilience and Sustainability ti È̩ka Legal ti Wikimedia Foundation. Ẹgbẹ́ náà ní òṣìṣẹ́ ìpilẹ̀sẹ̀ Strategy Àjọṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn olùṣètò tí ó dá lórí àwọn iṣẹ́-àkànṣe wiki, àwọn èdè àti agbègbè. Àwọn olùṣètò nso àwọn olùfarajìn, àwọn ará àti ẹ̀ka pọ̀ mọ́ àwọn iṣẹ́ wa, láti gba èsì àti èrò sílẹ̀, àti láti f'etí sí àwọn ìpèníjà wọn. Àfojúsùn wa ni láti ní òye ọ̀kan àti ìpohùnpọ̀ lórí bíí a ṣ'elè so àwọn èrò strategy d'àṣà.

Kọ́ si nípa ẹgbẹ́ yìí lórí ojú-ewé ẹgbẹ́ Movement Strategy and Governance.

Ohun tí à nṣe

Iṣẹ́ ẹgbẹ́ Movement Strategy and Governance ma ntẹ̀lé ìlànà Annual Plan ti Wikimedia Foundation. Annual Plan yìí ma nṣe àtìlẹ́yìn fún Ìdàgbàsókè Àjọṣepọ̀ kárí Ìjọba àwọn ará àti àwọn ètò àtìlẹ́yìn tó jọmọ́ ọ.

Àwọn Èróngbà

  1. Ṣíṣe àtìlẹyìn fún Movement Strategy governance láti ṣe àyípadà fún ìkópa tó dọ́gba
  2. Ṣe ìwúrí fún àgbéwọlé àwọn èrò lát'ọ̀dọ̀ àwọn ará àjọṣepọ̀ ọgbọ̀n, ókéré jù
  3. Fífi àyè sílẹ̀ fún Movement Strategy grants fún àwọn ẹgbẹ́ àti ará àjọṣepọ̀, ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú ẹgbẹ́ Community Resources.
  4. Ìrídájú àyè síbẹ̀ fún àwọn àlàyé àti ọ̀rọ̀ lórí àwọn ànfààní tó wà láti gbé Strategy Àjọṣepọ̀ lọ síwájú.

Àwọn iṣẹ́ míràn

  1. Ìkànsí àti àtìlẹyìn fún Ìgbìmọ̀ elétò Ìdìbò àti àwọn olùfarajìn ìdìbò láàri Ètò Ìdìbò fún Àwọn Onígbọ̀wọ́ Wikimedia Foundation 2021.
  2. Àtìlẹ́yìn fún àwọn ìlànà gbòógì titun. Lára rẹ̀ ni ṣíṣètò àwọn èsì pẹ̀lú ẹgbẹ́ Ìlànà Trust and Safety fún ètò ìgbófìnró Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí. Eléyìí gbé ìgbàsílẹ̀ àwọn ará àjọṣepọ̀ 25, ókéré jù yọ.

Bí a ṣé nṣe àtìlẹyìn fún Foundation

The MSG team provides several types of support to community-oriented programs. These programs are typically determined as part of the Annual Plan.

  • Multilingual and multi-regional Movement engagement in targeted topic areas:
    • Engaging in 10 major Wikimedia project languages; more languages are possible depending on availability of facilitators and pre-approved requests.
    • Regional coverage of Wikimedia major regions: ESEAP, South Asia, MENA, East Africa, West Africa, CEE, Western Europe, Latin America, and North America.
    • Support for specific countries is possible depending on availability of facilitators and pre-approved requests.
  • Facilitation of community processes such as conversations and elections, with a focus on diversity, equity, and inclusion.