Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí/Ìkànsí àti ìjíròrò àwọn alákòso/Oṣù kẹ́fà àti oṣù kéjèe 2021

From Meta, a Wikimedia project coordination wiki
Jump to navigation Jump to search
This page is a translated version of the page Universal Code of Conduct/Functionary consultations/June and July 2021 and the translation is 23% complete.
Outdated translations are marked like this.
Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí

Èrèdí

Ìlànà ìgbófìnró Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí nílò ètò. Èrèdí àwọn ìpàdé yìí ni fún àwọn oníṣẹ́ tí ó ní àwọn ohun èlò alákòso tàbí tí wọ́n já fáfá lórí àwọn ààyè kárí-ayé, láti jókò pọ̀ láti jíròrò àwọn ìkòrí mẹ́tàa tí ó jọmọ́ ètò: Bí ó ṣe yẹ́ kí àwọn ètò ìlànà yìí jẹ́, bí ati lè gbìyànjú láti má fi àyè gba ẹlẹ́yà mẹ̀yà, àti ibi tí óyẹ ká ti bẹ̀rẹ̀. Ìpàdé kọ̀ọ̀kan yíò wáyé fún wákàtí méjì, yíò o sì ní àwọn ìpín sí àwọn yàrá fún ìjíròrò lórí àwọn àkòrí kọ̀ọ̀kan, tí wọn yóò sì jábọ̀ fún àwọn ará tó kù láti ṣe ìpín nínú àwọn èrò náà. Lẹ́yìn àwọn oríṣìriṣí ìpàdé náà, a ó s'ètò àwọn ìgbésẹ̀ tókàn láti gbàsílẹ̀ àwọn èrò tí a fẹ́ tẹ̀ sí'wájú àti bíí a ṣe lè jùmọ̀ ṣe wọn paàpọ̀.

The Universal Code of Conduct's enforcement pathways will need structure. The purpose of these meetings are for users who are advanced rights holders on wikis or are active across the global space to get together and discuss three main areas related to structure: what can these potential structures look like, how can we build them to be representative and inclusive, and where do we begin. Each meeting will last around two hours, and will largely consist of breakout groups to talk about these points and then report back to each other and share ideas. After the series of meetings, we'll organize next steps to identify which ideas we want to pursue and how to do it together.

Àwọn ọjọ́ àti ago

Kò yẹ kí àwọn ọjọ́ yìí yẹ̀. A sì npinnu lórí àwọn ago.

Àwọn ẹgbẹ́ Ọjọ́ Ago
Àwọn Steward/Global Sysop 26 Oṣù kẹ́fà
Àwọn Arbitrator 26 Oṣù kẹ́fà
Àwọn Checkuser/Oversighter 27 Oṣù kẹ́fà
Àwọn Functionary tó ti lọ 27 Oṣù kẹ́fà
Àwọn alábòjútó wiki kékeré 10 Oṣù kéjèe
Àwọn Admin ti Emerging Communities 10/11 Oṣù kéjèe

These dates are unlikely to change. The times are still being determined.

Groups Date Time
Stewards/Global Sysops 26 June 15:00 UTC
Arbitrators 26 June 17:00 UTC
Checkusers/Oversighters 27 June 15:00 UTC
Small Wiki Monitoring Team 10 July 15:00 UTC
Quora of Admins from Emerging Communities 11 July 15:00 UTC

Post-meeting summary

The meetings were lightly attended but had useful conversations. Part of the meetings overlapped with global movement strategy conversations, and meeting attendees are also invested in those discussions. There was mainly talk about local processes in handling and reporting harassment and related user conduct issues on-wiki, gathering use cases for specific communities and groups that may need to adjust or create new processes to deal with UCoC related complaints. There were questions and answers about the role of community in creating and owning these processes, and how much time it will take to accomplish these goals. Attendees also shared and learned about how different communities are handing things already, and what can be emulated in other places.

There will be another round of discussions after the publication of the UCoC enforcement draft. The next round of meetings will push for heavier attendance and participation as the members of the groups have some something of substance to discuss and work with, having a draft available.

Information about signing up

If you are a member of more than one group and can attend multiple meetings, you're encouraged to sign up for as many as you qualify for. Each meeting is meant to gather information for what that particular group might want or need from the UCoC, and attending multiple meetings will provide the opportunity to share multiple perspectives if you participate in more than one area.

Former rights holders in good standing with their communities are welcome to join with their former groups as invited.

Àwọn Olùkọ́pa

Àwọn Steward àti Global Sysop

Àwọn Arbitrator


Àwọn CheckUser/Oversighter

Àwọn alábòjútó wiki kékeré


Àwọn Admin ti Emerging Communities