Jump to content

Ìpadé àpérò strategy gbogbo Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀ tí ó wáyé ní inú ọdún 2020

From Meta, a Wikimedia project coordination wiki
This page is a translated version of the page West Africa Strategy Meetup 2020 and the translation is 94% complete.
Outdated translations are marked like this.

Ìpàdé àpérò yí ni ó dá lé ìfohùn-ṣọ̀kan awọn oníṣẹ́ Wikimedia ni gbogbo Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀, láti lè jẹ́ kí gbogbo awọn ọmọ ilẹ̀ Adúláwọ̀ ó lè kópa tí ó lààmì-laaka àti kí ìbáṣeoọ̀ tó mọ́yán lórí ó láàrín ajọ Wikimedia àti awọn oníṣẹ́ Wikimedia jákè-jádò Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀.

Àwọn kókó ọ̀rọ̀ tí ó ṣe pàtàkì

 • Déètì: ọjọ́ Kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù Kẹwàá ọdún 20209
 • Ibi yí ó ti wáyé: "Zoom"
 • Àkálẹ̀ fọ́rán fídíò [$ur|Zoom]
 • Notes: [$ur| Notes Link]
 • Iye àwọn olùkópa: 92


Àfojúsùn

Àpérò Àmúse-múlò gbogbo gbò ilẹ̀ Adúláwọ̀ ni wọ́n ṣe láti lè mú awọn àfojúsùn wọ́nyí ṣẹ:

 1. Láti lè jẹ́ kí àwùjọ àwọn oníṣẹ́ ó lè kópa
 2. Ṣíṣe akọsílẹ̀ awọn èrò ati bí a ṣe lè mú awọn èrò àmúṣe-múlò(strategy).
 3. Ṣiṣẹ́ ìpolongo àwọn ìgbésẹ̀ àti ìròyìn nípa ọ̀nà àmúṣe-múlò (strategy) fún àwọn oníṣẹ́ àwọn Wikimedia ní Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀.
 4. Ṣiṣẹ́ àmójútó

Àwọn olùkópa
 1. Abderamane Abakar Brahim
 2. Abdulfatai Mustapha 
 3. Abigail York
 4. Aboubacar Keita
 5. Adaora Obuezie
 6. Adebayo Fawaz Tairou
 7. Ahmat Mahamat Tahi
 8. Amanda Keton
 9. Antoni Mtavangu
 10. Aquila Ayo
 11. Ayokanmi Oyeyem
 12. Azibert Abdallah
 13. Bobby Shabangu
 14. Bukola James
 15. Candy Khohliwe
 16. Chima Asogwa
 17. Chinelo Okonkwo-Chukwunweike
 18. Chris Azorbli
 19. Constance Azogbonon
 20. Douglas Erunayo
 21. Dumisani Ndubane
 22. Ebuka Hero
 23. EGBUNIWE CYNTHIA
 24. Emmanuel Yeboah
 25. Enock Seth Nyamador
 26. Erina Mukuta 
 27. Espérance HOUNNOU
 28. Euphemia Uwandu
 29. Faith Mwanyolo 
 30. FAUZIYAH NIHINLOLAWA ADENEKAN 
 31. Felix Nartey
 32. Friday Udeji 
 33. Gbemisola Esho
 34. Geoffrey Kateregga
 35. Gilbert Ndihokubwayo
 36. Haruna Shu'aibu
 37. Hugues Coba
 38. Iddy John
 39. Isaac Olatunde
 40. James Bondze
 41. Jamima Antwi
 42. Janeen Uzzell
 43. Jemima Antwi
 44. Jesse Akrofi 
 45. John Obell
 46. Jonathan Oberko
 47. Joris Quarshie 
 48. Joy Agyepong
 49. Justice Okai-Allotey 
 50. Kaarel Vaidla
 51. Kamaluddeen Isa El-Kalash
 52. Katherine Maher
 53. Kayode Yussuf
 54. Leonard Kisuu
 55. Lisa Steitz-Gruwell
 56. Maxwell Beganim
 57. Mehrdad Pourzaki
 58. Mikaeel Sodiq
 59. Mo Ajala 
 60. Mohammed Alliyu
 61. Nadaine Samira Iddrisu
 62. Nebiyu Sultan
 63. Nerus KOLADE
 64. N'fana DIAKITE
 65. Ngozi Perpetua
 66. Nkem Osuigwe
 67. Noreen
 68. Obiageli Ezeilo
 69. Oboubé Blanchard DJOSSOU
 70. Oby Ezeilo
 71. Onyinye Onuoha
 72. Rachad Sanoussi
 73. Rajeeb Dutta
 74. Rebecca Adengbono
 75. Ruby D-Brown
 76. Ryan Merkley
 77. Sadik Shahadu
 78. Sam Oyeyele
 79. Sami Mlouhi
 80. Sandister Tei
 81. Selorm Ayikoe
 82. Selorm Danyo 
 83. Stella Agbley
 84. Stephen Dakyi
 85. Tochi Precious
 86. Uzoma Ozurumba
 87. Valentin Nasibu
 88. Wilson Oluoha
 89. Winnie Kabintie 
 90. Yamen Bousrih
 91. Yves Sefu Madika
 92. Zita Sage

Àwọn ohun èsì tí a ń retí lẹ́yìn àpérò náà

A ń retí kí àwọn ìgbìmò alámòójútó àwùjọ àwọn oníṣẹ́ Wikimedia ní Ìwọ̀ Oòrùn ilẹ̀ Adúláwọ̀ ó tún ṣe ìpàdé ẹlẹ́kùn ò jẹkùn ní àwùj wọn ṣáájú ìpadé àpérò àpapọ̀ gbogbo àwọn Oníṣẹ́ àti ajọ Wikimedia lágbàáyé ní 21 sí 22 oṣù Kọkànlá ọdún 2020. Lẹ́yìn ìpàdé àpérò gbogbo gbò yí, awọn alámòójútó àwùjọ ẹkùn kòọ̀kan tún lè gbé ìpàdé mìíràn kalẹ̀ lẹ́yìn ìpàdé gbogbo gbò yí ní àwùjọ wọn láti lè tún mú ìlọsíwájú bá ọ̀nà àmúṣe-múlò àti èrò àjọ Wikimedia lápapọ̀ lẹ́kùn wọn.