Jump to content

Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ ti Wikimedia Foundation/Ìpè fún èrò: Ètò ìdìbò fún Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́

From Meta, a Wikimedia project coordination wiki
Outdated translations are marked like this.

Ìṣòro tí a fẹ́ yanjú

Wikimedia Foundation àti àjọṣepọ̀ yìí ti dàgbà ní ìwọ̀n ọdún mẹ̀wàá tí ó kọjá, ṣùgbọ́n ìgbìmọ̀ sì ti wà ní ìgbékalẹ̀ àti ètò kan. Ní ìwádìí governance 2019, agbára, iṣẹ́ ṣíṣe, àti àìní asojú fún onírúurú ará àjọṣepọ̀ wà lára àwọn ìfíyèsí.

Ní 2021, a jíròrò lórí àwọn ìfiyèsi wọ̀nyí ní Ìpè fún èrò: ìjókòó Ìgbìmọ̀ fún ará. Ìdìbò fún Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ 2021 ní ìṣe tó dára jùlọ láti dáhùn àwọn ìfiyèsí tí a là kale. ìjókòó méjì ni a fi kún Ìgbìmọ̀ láti pèsè fún àìní Ìgbìmọ̀ náà. A lo ètò ìdìbò STV láti gbòòrò ìṣojú onírúurú àjọṣepọ̀. Àwọn Ìgbìmọ̀ pín àwọn ọgbọ́n wọn, wọ́n sì bèrè kí àwọn olùdíje pín ti wọn náà láti fi tó àwọn ará létí. Ètò ìkànsí tó gbòòrò ni a fi wá àwọn olùdíje àti olùdìbò káàkiri àjọṣepọ̀ lórí oríṣiríṣi àẉon pẹ́pẹ́ ìkéde.

Lákòókò Ìpè fún èrò 2022 yìí, a ní ìrètí wípé a ó rí àwọn ọ̀nà àbáyọ míràn láti fi ìrísí fún iye onírúurú àwọn ará lórí Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́. Pẹ̀lúpẹ̀lú, a fẹ́ lo ànfààní yìí láti kọ́ lọ́dọ̀ àwọn ará bíí aṣelè ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú àwọn olùdíje láàrin ètò ìdìbò náà.

Irú Ìpè fún èrò

Pẹ̀lú Ìpè fún èrò èyí, à n lo ọ̀nà míràn tí yí o da èrò àwọn ará pọ̀ mọ́n ètò 2021. Dípò ṣíṣe ìdarí pẹ̀lú àwọn àbá, ìpè yìí o tẹ̀lé ìlànà àwọn ìbéèrè gbòógì. À ngbèrò láti ṣe ìwúrí fún ìjíròrò àti ìdàgbàsókè àbá lórí àwọn ìbéèrè wọ̀nyí.

Adúpẹ́ fún àkókò tí ẹ fi kópa nínú Ìpè fún èrò yìí àti ìrànlọ́wọ́ láti dásílẹ̀ Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ tó ní onírúurú ènìyàn àti tí ó n ṣisẹ́ dára dára.

Àwọn ìbéèrè gbòógì

  1. Kíni ọ̀nà tó dára jùlọ láti rí dájú wípé ìsojú onírúurú wà láàrín àwọn ẹni tí a bá dìbò fún?
  1. Kíni à nre tí lát’ọ̀dọ̀ àwọn olùdíje láàrin ètò ìdibò náà?
  1. How should affiliates participate in the elections?

ṣe ìjíròrò àwọn ìbéèrè gbòógì

Bí o ṣe lè kópa

Movement Strategy and Governance staff are able to support conversations in many languages. Discussions are welcome in any language, although we may need to rely on volunteer translators to help summarize languages we do not have on staff. You can find links to conversations in many languages in a table on the Discuss Key Questions page. You can find conversation on the Telegram Board selection chat. Contact a facilitator in your region to plan a community conversation or provide feedback.

Ago-iṣẹ́

  • 23 December: Ìkéde Ìpè fún Èrò
  • 10 January: Ìpè fún èrò sí sílẹ̀
  • 16 February: Ìpè fún èrò sí parí
  • 26 February: Ṣ’àtẹ̀jáde àkópọ̀ ìparí Ìpè fún èrò

Ní ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀, ẹgbẹ́ Strategy Àjọṣepọ̀ àti Governance yí ó ṣe àtẹ̀jáde ìjábọ̀ ọ̀sọ̀ọ̀sẹ̀ láti ṣe ìròyìn àwọn èsì àti ìjíròrò tó wáyé láàrín ọ̀sẹ̀ tó kọjá.

Àlàyé ọ̀rọ̀ tó wúlò

The Board of Trustees is the governing body for the Wikimedia Foundation, a +450 staff organization supporting an international movement formed by hundreds of projects, communities, and affiliates. The Board’s sole role is to oversee the management of the Wikimedia Foundation. This includes:

  • Kíkópa nínú ìṣètò Strategy ìgbà-gígùn Wikimedia Foundation
  • Ṣe àbojútó àwọn iṣẹ́ àti ìṣúná láti ríi dájú wípé ètò ìṣúná wà ní ìlera, nṣe déédé pẹ̀lú iṣẹ́ wa àti àwọn òfin àgbáyé.
  • Ìgbaniṣiṣé, ìṣàkóso, ìgbìyànjú, àti sísanwó iṣẹ́ fún CEO Wikimedia Foundation.

Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ọ̀rọ̀ wà lórí Ìwé ìgbìmọ̀.

tún wo