Wikimedia Foundation elections/2021/2021-08-27/Second board voter e-mail/yo

From Meta, a Wikimedia project coordination wiki
This page is a translated version of the page Wikimedia Foundation elections/2021/2021-08-27/Second board voter e-mail and the translation is 100% complete.

From: Ìgbìmọ̀ Ètò Ìdìbò Wikimedia Foundation <board-elections@lists.wikimedia.org>

Rántí láti dìbò nínú ètò ìdìbò fún Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbòwó Wikimedia Foundation

Olùfẹ́ $USERNAME,

Ò ngba ìwé yìí nítorí o ní àṣẹ láti dìbò nínú ètò ìdìbò fún Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbòwó Wikimedia Foundation ti 2021. Ètò ìdìbò yìí bẹ̀rẹ̀ ní 18 August 2021, yí ò sì parí ní 31 August 2021.

Wikimedia Foundation nṣiṣẹ́ lórí àwọn iṣẹ́-àkànṣe bíi $ACTIVEPROJECT pẹ̀lú ìdarí Ìgbìmọ̀ Onígbọ̀wọ́. Ìgbìmọ̀ yìí ni aláṣẹ Wikimedia Foundation. Kọ́ si nípa Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́.

L'ọ́dún yìí, a ó yan ìjókò mẹ́rin nípasẹ̀ ìdìbò àwọn ará. Àwọn olùdíje mọ́kàndínlógún káàkiri àgbáyé ni ó n díje fún àwọn ìjókò wọ̀nyí. Kọ́ si nípa àwọn olùdíje fún Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ ti 2021.

À nbèrè fún ìbò àwọn ará àjọṣepọ̀ tó fẹ́ẹ̀ tó 70,000. Lára wọn ní ìwọ́jẹ́! Àyè àti dìbò yí ò wà títí di 23:59 UTC August 31. Lọ sí [$SERVER/wiki/Special:SecurePoll/vote/Wikimedia_Foundation_Board_Elections_2021 SecurePoll lórí $ACTIVEPROJECT] láti dìbò.

Tí o bá ti dìbò tẹ́lẹ̀, a dúpẹ́ fún ìbò rẹẹ, jọ̀wọ́ paa ìwé yìí tì. È̩ẹ̀kan ni àwọn ènìyàn lè dìbò.

Ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ lórí ìdìbò yìí.

Pẹ̀lú ìfọwọ́sí,

Ìgbìmọ̀ Elétò Ìdìbò

This mail has been sent to you as you have registered your email address with the Wikimedia Foundation. To remove yourself from future election notifications, please add your user name to the Wikimedia No Mail List.

Plain text version

Olùfẹ́ $USERNAME,

Ò ngba ìwé yìí nítorí o ní àṣẹ láti dìbò nínú ètò ìdìbò fún Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbòwó Wikimedia Foundation ti 2021. Ètò ìdìbò yìí bẹ̀rẹ̀ ní 18 August 2021, yí ò sì parí ní 31 August 2021.

Wikimedia Foundation nṣiṣẹ́ lórí àwọn iṣẹ́-àkànṣe bíi $ACTIVEPROJECT pẹ̀lú ìdarí Ìgbìmọ̀ Onígbọ̀wọ́. Ìgbìmọ̀ yìí ni aláṣẹ Wikimedia Foundation. Kọ́ si nípa Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́: <https://meta.wikimedia.org/wiki/Wikimedia_Foundation_Board_of_Trustees/Overview>

L'ọ́dún yìí, a ó yan ìjókò mẹ́rin nípasẹ̀ ìdìbò àwọn ará. Àwọn olùdíje mọ́kàndínlógún káàkiri àgbáyé ni ó n díje fún àwọn ìjókò wọ̀nyí. Kọ́ si nípa àwọn olùdíje fún Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ ti 2021: <https://meta.wikimedia.org/wiki/Wikimedia_Foundation_elections/2021/Candidates#Candidate_Table>

À nbèrè fún ìbò àwọn ará àjọṣepọ̀ tó fẹ́ẹ̀ tó 70,000. Lára wọn ní ìwọ́jẹ́! Àyè àti dìbò yí ò wà títí di 23:59 UTC August 31. Lọ sí SecurePoll lórí $ACTIVEPROJECT láti dìbò: <$SERVER/wiki/Special:SecurePoll/vote/Wikimedia_Foundation_Board_Elections_2021>

Tí o bá ti dìbò tẹ́lẹ̀, a dúpẹ́ fún ìbò rẹẹ, jọ̀wọ́ paa ìwé yìí tì. È̩ẹ̀kan ni àwọn ènìyàn lè dìbò.

Ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ lórí ìdìbò yìí: <https://meta.wikimedia.org/wiki/Special:MyLanguage/Wikimedia_Foundation_elections/2021/Board_of_Trustees>.

Pẹ̀lú ìfọwọ́sí,

Ìgbìmọ̀ Elétò Ìdìbò

--

This mail has been sent to you as you have registered your e-mail address with the Wikimedia Foundation. To remove yourself from future election notification, please add your user name to the Wikimedia No Mail List 
<https://meta.wikimedia.org/wiki/Wikimedia_nomail_list>.