Jump to content

Ètò Ìdìbò Wikimedia Foundation/2021/2021-09-07/Èsì Ìdìbò 2021/Kúkúrú

From Meta, a Wikimedia project coordination wiki
This page is a translated version of the page Wikimedia Foundation elections/2021/2021-09-07/2021 Election Results/Short and the translation is 100% complete.

The election ended 31 Oṣù Kẹjọ 2021. No more votes will be accepted.
The results were announced on 7 Oṣù Kẹ̀sán 2021. Please consider submitting any feedback regarding the 2021 election on the elections' post analysis page.

2021 Board Elections
Main Page
Candidates
Voting information
Single Transferable Vote
Results
Discussions
FAQ
Questions
Organization
Translation
Documentation
This box: view · talk · edit

Èsì fún ètò ìdìbò Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ Wikimedia Foundation tí ó gbajúmọ̀ jùlọ

Adúpẹ́ lọ́wọ́ gbogbo ènìyàn tó kópa nínú ètò ìdìbò 2021. Ìgbìmọ̀ elétò ìdìbò ti ṣe àgbéyẹ̀wò àwọn ìbò fún Ìdìbò Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ Wikimedia Foundation 2021, tí wọ́n ṣ'ètò láti yan àwọn alága mẹ́rin titun. Àwọn ènìyàn 6,873 káàkiri àwọn iṣẹ́-àkànṣe 214 ni ó fi ìbò sílẹ̀. Àwọn olùdíje mẹ́rìn yìí ni ó borí:

  1. Rosie Stephenson-Goodknight
  2. Victoria Doronina
  3. Dariusz Jemielniak
  4. Lorenzo Losa

Nígbàtí ati yan àwọn olùdíje nípasẹ̀ ìdìbò ará àjọṣepọ̀, Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ kò tí yàn wọ́n. Wọ́n síbẹ̀ ní láti yege àwọn ìwádìí abẹ́lẹ̀ nípa wọn àti yege nínú àwọn òfin tí ó yẹ. Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ ti gbà láti yan àwọn alága titun ní ìparí oṣù yìí.

Ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìkéde níbí.