Jump to content

Ìdìbò Wikimedia Foundation ti ọdún/2021

From Meta, a Wikimedia project coordination wiki
This page is a translated version of the page Wikimedia Foundation elections/2021 and the translation is 30% complete.
Outdated translations are marked like this.

The election ended 31 Oṣù Kẹjọ 2021. No more votes will be accepted.
The results were announced on 7 Oṣù Kẹ̀sán 2021. Please consider submitting any feedback regarding the 2021 election on the elections' post analysis page.

2021 Board Elections
Main Page
Candidates
Voting information
Single Transferable Vote
Results
Discussions
FAQ
Questions
Organization
Translation
Documentation
This box: view · talk · edit

The 2021 Board of Trustees election has been rescheduled to 18 – 31 August 2021 due to technical issues with SecurePoll. Read more.

Ìdìbò sí ipò Board of Trustees ti ọdún 2021 ni a ń retí kí ó wáyé ní ọjọ́ Kẹtàdínlógún oṣù Kẹjọ ọdún 2021. Gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ Wikimedia pátá ni ó ní ànfaní láti yan aṣojú mẹ́rin tí wọn yóò ṣojú wọn fún ọdún mẹ́ta gbáko. Àyè yóò ṣí sílẹ̀ láti Ma dìbò ní ọjọ́ Kẹsàn án oṣù Kẹfà ọdún 2021. Ó ṣe é ṣe kí ọjọ́ tí a mú yí ó yẹ̀.

Candidate Table

Please click on a candidate's name to learn more.

Voting

Voting was from 18 August 2021 to 31 August 2021. Voting information and instructions are on the Voting information page.

Note: If your vote is rejected, don't try logging in on votewiki. Instead, if the system rejects a valid vote, you should just restart the voting process. Since the voting form will be blank again, it is a good idea to write down your choices in a separate document or take a screenshot before submitting the form.

Learn more about the Board of Trustees in this short video:

Àwọn àsìkò tí wọn yóò wáyé

 • 2021-04-15Ìpinu àwọn ìgbìmọ̀ lórí ètò ìdìbò
 • 2021-04-29Elédè fún ìkòpa àwọn olùrànwọ́ ìbò
 • 2021-96-09 sí 2021-06-29 Ìkéde àwọn Olùdíje
 • 2021-06-30 sí 2021-07-02 Ìkéde àwọn olùdíje tó peregedé
 • 2021-07-97 sí 2021-08-03 Ìpolongo ìbò
 • 2021-08-04 Ìbò dídì bẹ̀rẹ̀
 • 2021-08-17 Ìbò dídì kásẹ̀ nílẹ̀
 • 2021-08-18 sí 2021-08-24 Ìbò kíkà
 • 2021-08-25 Ìkéde èsì Ìbò
 • Ìyànsípò àwọn ènìyàn kan yóò wáyé ní inú oṣù Kẹsàán 2021.
Board of Trustees election timeline

The Board election facilitators created a graphic of the timeline. This can be used to share information about the election. The graphic is available in more languages.

Campaign Activities

This is a list of campaign activities planned during the campaign period. Further activities are in the making, the list will be updated continuously. Community members are welcome to add additional activities to the list below. If you add activities, please link to the page where community members can find more information.

Ìpolongo

Iye àwọn òndìbò tí wọ́n kópa nínú ìdìbò ti ó kọjá tó ìdá mẹ́wàá gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ Wikimedia lágbàáyé. Ohun tí ó jẹ́ kí ó rọrùn ni bí àwọn kan ṣe fínú-fíndọ̀ láti kún ìdìbò náà lápá. Púpọ̀ nínú àwọn ọmọ ẹgbẹ́ àwùjọ kòọ̀kan jẹ́ èdè ogún.

Àwọn tí wọ́n lè jọ̀wọ́ ara wọn sílẹ̀ fún ètò ìdàibò

Njẹ́ o lè ṣe ìrànwọ́ọ́ bí àwọn òndìbò yóò ṣe pọ̀ si ní àwùjọ rẹ bí? Láti ṣe èyí, o kò ní láti ní inọ̀ nípa ètò ìdìbò tẹ̀lẹ́. Olùranwọ́ lè jẹ́ kí ìkópa àwọn òndìbò ó ra gọ́gọ́ si ní àwùjọ wọn. Gbogbo oníṣẹ́ Wikimedia ní gbogbo àwùjọ agbáyé ni ó lè dara pọ̀ mọ́ iṣẹ́ yí! Ó wù wá kí á ri olùrànwọ́ kan tí yóò dúró láti di ètò ìdìbò jkan mú nínú àwọn iṣẹ́ àkànṣe Wikimedia pátá. Onítòhún yóò sì lè jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìgbìmọ̀ olùfọkàn tán pẹ̀lú bí ipa rẹ̀ yóò ṣe mú àwọn ènìyàn àwùjọ rẹ̀ dìbò!

Ìbára-ẹni-sọ̀rọ̀

Oríṣiríṣi ifọ̀rọ̀-jomi-toro ọ̀rọ̀ ni no lọ lọ́wọ́ lọ́wọ́ nípa àwọn ìgbìmọ̀ Olùfọkàntán ìbò jákè-jádò agbáyé. Ìwọ náà, dara pọ̀ mọ́ wa!

Bí a ṣe ń ṣe àṣàyàn àwọn ènìyàn sí ipò náà lórí Ìtàkùn ìbánisọ̀rọ̀ Telegram
Nínú iyará ìbánisọ̀rọ Telegram yí ni àwọn ikọ̀ amúṣẹ́ṣe yóò ti ma fi ohun tí ó kan tó wa létí
Àwọn olùrànwọ́ ìbò láti Aríwá Asia
Fi Ìtàkùn tí àwọn ènìyàn lè lò láti dara pọ̀ mọ́ ìjíròrò yí ní àwùjọ rẹ

Àwọn Ikọ̀

Àwọn Ìgbìmọ̀ ètò ìdìbò
AbhiSuryawanshi
Carlojoseph14
HakanIST
KTC
Mardetanha
Masssly
Matanya
Ruslik0
Àwọn ikọ̀ amúṣẹ́ṣe
Quim Gil Alákòóso
Xeno: English communities and Meta-Wiki
Jakie Koerner-Alskòóso fún Wikipedia èdè Gẹ̀ẹ́sì ati Meta-Wiki
Civvi: Italian communities
Oscar Costero-Alskòóso fún àwùjọ agbègbè Latin Amerika
Mahuton Possuouope-Alákòóso fún àwùjọ Wikipedia Faransé
Zita Zage - Alákòóso fún gbogbo Sub-Saharan Africa
Denis Barthel- láti àwùjọ Wikipedia ede Gamaní ati North ati Western Europe lápapọ̀
Ravan Al-Taie- Alákòóso fún àwùjọ Wikimedians Medile East ati agbègbè Africa
Krishna C.Velaga- Alákòóso fún àwùjọ South Asia
Mohammed Bachounda - Amúgbá-lẹ́gbẹ̀ẹ́ alákòóso fún àwọn àwùjọ elédè French àti MENA region
Mehman Ibragimov-Alákòóso fún Central àti Eastetn Europe
Sam Oyeyele: Yoruban communities and West Africa region
Vanj Padilla -Alákòóso fún àwùjọ East,South-East àti erékùṣù Pacific
Youngjin Ko: Korean communities and East Asia region
Ramzy Muliawan: Indonesian communities and Southeast Asia and the Pacific region

Agbékalẹ̀

Ìdìbò sí ipò Bourd of Trustees ni ó ya kí ó ti wáyé ní ọdún 2020, amọ́ ìgbìmọ̀ yí kéde rẹ̀ wípé àwọn sún ètò ìdìbò yan sí ipò yí siwájú. Ìgbìmọ̀ yí náà ni wọ́n tún kéde ìdìbò ní inú Kẹrin ọdún 2021, wọ́n sìn ń fẹ́ àjọṣepọ̀ gbogbo ọmọ ẹgbẹ́ Wikimedia jákè-jádò agbáyé

Láti lè fi aye gba ọ̀pọ̀ èrpò si ipò yí, Ìgbìmọ̀ yí da àyè mẹ́rìdínlógún míràn si fún àwọn tí wọ́n ní ẹ̀bùn ọlọ́kan-ò-jọ̀kan nínú láti gbé ajọ Wikimedia sókè si lágbàáyé.

Lára àwọn àyè mẹ́fà tí wọ́n dá sílẹ̀ ni:

 • 3 new Community-ati Affiliate Selected seats
 • 3 new Bourd-selected seats

Wọn yóò yan ènìyàn mẹ́rin sí àyè mẹ́tin ní ọdún 2021, mẹ́ta yóò yóò wà fún ìsọdọ̀tun àwọn tí wọ́n ti wà níbẹ̀ tẹ́lẹ̀, nígbà tí ẹlẹ́kẹrin yóò jẹ́ ti fífẹ ìkópa ìgbìmọ̀ náà siwájú si. Méjì yóò wà fún àwùjọ tuntun tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ fẹ́ dara pọ̀ ní inú ìdìbò ọdún 2022, pẹ̀lú méjì tí wọ yóò sọ dọ̀tun. Yóò jẹ́ mẹ́rin lápapọ̀.