Wikimedia Blog/Drafts/Inspire New Readers campaign: Raise awareness of Wikipedia where you live/yo

From Meta, a Wikimedia project coordination wiki
Jump to navigation Jump to search

Other languages:
English • ‎Hausa • ‎Yorùbá • ‎español • ‎português • ‎português do Brasil • ‎العربية • ‎हिन्दी • ‎ਪੰਜਾਬੀ • ‎ଓଡ଼ିଆ

Ìpolongo fún àwọn olùkà tuntun: Ṣe ìtànká Wikipedia ní agbègbè rẹ

Ìkádíì

Ìwádìí ìmọ̀ ọtun fihàn pé mẹ́tàlé-lọ́gbọ̀n ìdá ọgọ́rún nínú àwọn tí ó ń lo ayélukára ní ilẹ̀ India, tí ìdá mọ́kàndín -lógún ìdá ọgọ́rún tí ń lo ayélukára ní ilẹ̀ Iraq, àti ìdá mọ́kàndínlógójì àwọn tí ó ń lo ayélukára ní ilẹ̀ Brazil ló gbọ́ nípa Wikipedia. Iye àwọn òǹkà tí a mẹ́nu bà yìí yàtọ̀ gbáà sí ti orílẹ èdè Amẹ́ríkà àti Faransé, ní ibi tí ìdá mẹ́tàdínlọ́gọ́rin àtí mẹ́rìnlélọ́gorin tí àwọn tí ó ń lo ayélukára ní adáyanrí ti gbọ́ nípa Wikipedia. Báwo lo ṣe máa ṣe ìpolongo Wikipedia ní agbègbè rẹ? À ń ṣe ìpolongo lati gbọ́ àwọn èrò rẹ

Àkóónú

Ǹ jẹ́ o mọ̀ wípé ìdá mẹ́tàlé-lọ́gbọ̀n péré nínu ìdá ọgọ́rún nínú àwọn tí ó ń lo ayélukára ní ilẹ̀ India ní ó gbọ́ nípa Wikipedia? Bí eléyìí, ọ̀pọ̀lọpọ̀ agbègbè káà-kiri àgbáyé ni ìtànká Wikipedia ti mẹ́hẹ. Fún àpẹẹrẹ, ìdá mọ́kàndín -lógún péré nínú ìdá ọgọ́rún tí ń lo ayélukára ní ilẹ̀ Iraq, àti ìdá mọ́kàndínlógójì àwọn tí ó ń lo ayélukára ní ilẹ̀ Brazil ló gbọ́ nípa Wikipedia. Tí o bá ń gbé ní ọkan lára àwọn agbègbè tí a dárúkọ yìí, kí lo lè ṣe láti fa ojú àwọn olùkà tuntun mọ́ra sí Wikipedia?

A fẹ́ gbọ́ nípa àwọn èrò rẹ! Latí ọjọ́ -kẹjọ oṣù kíní sí ọjọ́ - kẹrin oṣù kejì, a máa ṣe ìpolongo olọ́pọ̀ èrò: Ṣe ìwúrí fún àwọn olùkà túntun. Kókó ìpolongo yìí ni láti mún àlékún bá ìtànká Wikipedia ní agbègbè rẹ. Títí di oṣù ti ó ń bọ̀, jẹ́ kí a mọ̀ nípa èrò rẹ, ṣe àpérò pẹ́lú àwọn akẹgbẹ́ rẹ kí o sì ṣètò iṣẹ́ àkànṣe lọ́rí bí o ṣe máa mú ìwúrí bá ìpolongo yìyí lórí Meta. lẹ́yìn ìpolongo yìí, àwọn ètò wà fún bí a ṣe lè sọ àwọn èrò wọ̀nyí dí iṣẹ́- àmúṣe. Fún àwọn iśẹ́ àkànṣe tí kò la ìnánwó lọ, ètò ìmúra àti àwọn oun tí a lè fi ràn ẹ lọ́wọ́ wà.


Why new readers?

kókó ìpolongo yìí ni láti ṣe àkójọ èrò nípa bí a ṣe le mú àlékún bá ìtànká Wkipedia. Ó tún jé ònà kan láti fa àwon olùkà tutun tí kò tíì lo Wikipedia rí wọ àwùjọ wa àti láti ràn wọ́n lọ́wọ́ láti mọ iṣẹ́ takun takun tí àwọn ọ̀gọ̀ọrọ̀ àwọn onísẹ́ ọfẹ́ ń ṣé láti kọ́ orísun ìmọ̀ tí ó tóbi jùlọ ní gbogbo àgbàyé.

This campaign is one of a series of Wikimedia Foundation projects that aim to increase awareness of Wikimedia projects. This work is vitally important: we know, based on recent research, that awareness of Wikipedia differs around the world. In the United and Western Europe, an average of 85 percent of internet users have heard of Wikipedia, that number drops sharply around the globe. Research also shows that only 33 percent of Internet users in India, 19 percent of internet users in Iraq, and 39 percent of Internet users in Brazil have heard of Wikipedia.


kíni ni pàtàkí ìpolongo yìí? Ipolongo ni ìgbésẹ̀ akọ́kọ́ nínú kíkọ́ àwọn aṣàmúlò tuntun, kún lápá, àti láti kópa tó lààmì laaka nínú àwon iṣẹ́ àkànṣe Wikipedia. A mọ wípé ìtaǹká Wikipedia tí ó kéré ni ó fàà tí àwọn aṣàmúlò rẹ̀ fi kéré, bí kò bá sì sí lílò rẹ̀ àwọn ènìyàn kò lè di olùdásí tàbí aṣojú fún ìwé im̀ọ ẹkọ ọ̀fẹ́ náà. lílẹ́tọọ́ sí ìmọ̀ jẹ́ ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn. Bí a ṣe láfojúsuǹ lórí ṣíṣàlékún ìkópa, bẹ́ ẹ̀ ni a jọ ń ṣiṣẹ pọ̀ lórí ẹ̀tọ́ sí pẹpẹ ìroyìn, àti pàápàá jùlọ fún oríṣiríṣi orísun ìmọ̀ níbi tí kálukú ti ní ipò nínú àkọślẹ̀̀ ìtàn.

Join the campaign!

Inspire Campaigns are month-long events to focus collaborative efforts on some of the most pressing challenges of the Wikimedia movement. This is a time to share and create new ideas, and there are many ways to participate: you can contribute your own ideas, give feedback on other people’s ideas, and sign up as a volunteer to help in other participant’s projects.

Resources are available to help you think through new ideas. You can find two videos explaining recent efforts that focus on awareness of Wikipedia in Nigeria and India on the campaign page. We will also be hosting two workshops: one on how to think about awareness, and another one on how to plan a pilot. Find the details and sign up to attend the workshops here.

Join the Inspire New Readers campaign and help us to bring the joy of Wikipedia to new readers around the world.María Cruz, Communication and Outreach Project Manager, Learning and Evaluation, Wikimedia Foundation

This Inspire campaign is being led by the Wikimedia Foundation’s Community Resources team with support from its New Readers team, which includes folks from Audiences, Communications, and Partnerships.

Submit your proposals starting 9 January!