Ẹkọ/Iroyin/Owara 2023/lẹta Idan:Ona ara otun fún ètò ẹkọ Wikipedia/Ojúewé
WiR Anglophone Bi-Weekly Webinar:Supercharging Your WikiEducation Programs through letters
Summary: Ni ogunjo Osu Owara 2023 Code For Africa Wikimedian in Residence Series Ṣawari "Ṣe afihan awọn eto WikiEducation rẹ nipasẹ awọn lẹta." Labẹ oludari Bukola James pẹlu ṣiṣe afihan Ruby Brown ti Open Foundation west Africa, eto na ni olukopa mejidinlogbon lati orisirisi ileto ẹkun adulawo ati oke-okun. Àkòrí òrò wá sí dálé lori bẹ ase le mu amugbooro deba Edu-Wiki ati ìwúlò pataki Oju iwe iroyin Edu-Wiki ni awujo Wikimedia
Ni ogunjo Osu Owara 2023 Code For Africa Wikimedian in Residence Series Ṣawari "Ṣe afihan awọn eto WikiEducation rẹ nipasẹ awọn lẹta." Labẹ oludari Bukola James pẹlu ṣiṣe afihan Ruby Brown ti Open Foundation west Africa, eto na ni olukopa mejidinlogbon lati orisirisi ileto ẹkun adulawo ati oke-okun. Àkòrí òrò wá sí dálé lori bẹ ase le mu amugbooro deba Edu-Wiki ati ìwúlò pataki Oju iwe iroyin Edu-Wiki ni awujo Wikimedia
Broadening Horizons
Our dedicated initiative aims at uplifting and empowering African Wikimedians. The recent session drew an enthusiastic participation of 28 members, representing diverse backgrounds from nations like Cameroon, Kenya, Uganda, Tanzania, and more. Their collective energy and knowledge made the event a great success.
📝 Key Takeaways from the Session
- Understanding Edu-Wiki: Ruby gave participants a lucid understanding of 'Edu-Wiki'. Bridging 'education' with 'Wiki', she emphasized its relevance in the Wikimedia education sector.
- The Power of Storytelling: Underlining the significance of narratives, Ruby spotlighted how newsletters can effectively be utilized to share compelling tales of Wikimedia education.
- EduWiki Newsletter's Journey: The legacy of the EduWiki Newsletter is rich. Since its inception in 2012, it has amassed 322 subscribers, consistently recording 600-700 monthly page views.
🚀 Benefits of Featuring in the EduWiki Newsletter
The platform offers a multifaceted advantage. Not only does it open a channel for sharing knowledge, but it also builds bridges for future collaborations and references, especially when vouching for one's involvement in the Wikimedia Education arena.
A pe Ogoro eniyan lati wa ba wa dasi lẹta wa ki ole ba gbórò ju bayi lo=
- Ekunrere iroyin nípa ètò ẹkọ tí o nṣe atọka awọn ipa Abi esi abajade
- Alaye lori ibasepọ ati àjọṣe tó mọ Yan lórí pèlú àwon ilé-èkó
- Pipolongo awọn eto ọlọkàn ojokan wa ti o nbọ laipẹ
- Agbeyewo awọn eto wa ti ati se séyìn pẹlu Oju sun ni kun
Owo idan to ọwá labẹ awọn iwe iroyin wa
Ṣíṣe atẹjade iwe iroyin ni ososu kise iṣẹ kékeré. Ọpẹ pataki lọwọ àwọn aladuro ti wa ti won je igi leyin ọgbà ti won ba wa se ayewo ,atun gbeyewo, atunko ati àtúnṣe awọn lẹta ati ọrọ ọlọkàn ojokan ti wonsi tun bawa ti palẹ sí orísirísi èdè tí ole rọrun fún eyin olugbo wa ni kika in gbogbo Ọgbọn Ọjọ Osu
Awọn Ona ti ale gba ko awon Itan wiki
Ruby fi oyaya so awọn ẹwà ati asiri lati ko awon Itan wiki:
- Mu Akori ọrọ ti o ba igba ati akoko mu ti awọn eniyan fẹ gbọ.
- Lilọ awọn ẹrọ ìgbàlódé lati fiṣe afihan itan bi fọto, awonran orisirisi pẹlu awọn oda alaranbara ti o je oju ni gbese
- Tele agbekale òfin itẹwe iroyin pẹlu agbekale to man Yan lórí
Awọn ọna asopọ ti wúlò to sise pataki
- wo awọn iroyin ni yajoyajo
- Bere kíkó iwe iroyin re
- Ekunrere alaye be àṣẹ le ko ìwé ìròyìn
- Gbigba Iwe iroyin wa oloso su
- Ni anfani sí Akọsilẹ awọn fanran ètò ẹkọ ti ati ko sẹyìn
🗣️ Participant Reflections
- The insights were invaluable. Fantastic session! — Jojo ck
- A revelation about the EduWiki newsletter. Eager for the next! — Alex Doe
🌱 Moving Forward
This webinar marked a notable milestone in our mission to amplify African Edu-Wiki narratives. By creating spaces of learning and collaboration, we aim to strengthen our community bonds and share impactful stories.
Darapọ Mọ àwọn olùgbọ wa; Register for our upcoming CfA WiR Bi-weekly webinar. Lati lẹ mọn nípa àwọn ẹtọ wa, Parapò mo awujo wa ti on dagba sókè ni gbogbo igba