Jump to content

User:Boysarm

From Meta, a Wikimedia project coordination wiki

Kosoko ( ọba of Lagos)

Kosoko kú ní ọdún 1872, ó jẹ́ ọ̀kan lára ẹbí ìdílé ọba Ológun kutere, tí ìpínlè èkó, tí ó jọba ìpínlè èkó láti ọdún 1845 títí dé ọdún 1851. Bàbá a rẹ̀ jẹ́ ọba Osinlokan, àwọn iyekan rè ni Idewu Ojulari ( tí ó jọba láti ọdún 1829 títí dé 1834/35), Olufunmi, Odunsi, Ladega, Ogunbambi, Akinsanya, Ogunjobi, Akimosa, Ibiyemi, Adebajo, Matimoju, Adeniyi, Isiyemi, Igbalu, Oresanya àti Idewu-Ojulari.