Movement Charter/Content/Global Council/yo

From Meta, a Wikimedia project coordination wiki
This page is a translated version of the page Movement Charter/Content/Global Council and the translation is 27% complete.
Outdated translations are marked like this.

Awon ohun to sele

Àti se atungbeyewo Igbekale ati bi ise se nlo ti tele lati le fun igbimo agbaye ni agbara ipinnu sise. Afojusun eto yii ni lati tun agbara pin laarin egbe yii. Ìgbésẹ̀ yii ni í ṣe pẹelu mimu àwọn ilé tuntun ṣe àtúnṣe sí àwọn ilé tó wà nísinsìnyí. Ti agbara ti o po ju kuro lati ajo Wikimedia foundation si awon ajo alapero ti igbimo agbaye.

Itumo

Ìgbìmọ̀ Àgbáyé ni ìgbìmọ̀ ìṣàkóso tó ń bójú tó ìdàgbàsókè àti ìmúṣẹ ètò ìyípadà, títí kan ìròyìn ọdọọdún nípa àwọn ohun tó jẹ́ ojúṣe pàtàkì lágbàáyé fún ètò Wikimedia. Àwọn olùyọ̀ǹda ara ẹni ló wà nínú ìgbìmọ̀ yìí, àwọn òṣìṣẹ́ sì ń tì wọ́n lẹ́yìn. Àwọn olùyọ̀ǹda ara ẹni tó wà nínú Ìgbìmọ̀ Àgbáyé wá láti onírúurú àwọn olùrànlọ́wọ́ nínú ìgbìmọ̀ Wikimedia. Ìgbìmọ̀ Àgbáyé ń mú kí ìsọfúnni àti ìfòyemọ̀ nípa àwọn ìpinnu tó ń wáyé ní gbogbo àgbègbè ìgbìmọ̀ náà túbọ̀ dára sí i. Ó ń mú kí wọ́n lè wọ àwọn ohun ìní Ìgbìmọ̀ náà lọ́nà tó rọrùn, ó sì ń fún àwọn èèyàn àti àwùjọ lómìnira láti ní ìgbọ́kànlé láàárín àwọn tó ní í ṣe pẹ̀lú ètò náà. Ìgbìmọ̀ Àgbáyé ń gbé àwọn ohun tó ní lọ́kàn lárugẹ nípa mímú àwọn ìlànà àti àwọn àfojúsùn tó wà fún àwọn ìgbìmọ̀ káàkiri àwọn ìgbìmọ̀ náà ṣẹ, ó ń bójú tó wọn, ó sì ń fúnni ní àwọn ìpinnu àti àwọn ìtọ́ni tó wà fún ìgbìmò̀ tó ń múni ṣẹ ní àfikún sí i.

Idi

A dá Ìgbìmọ̀ Àgbáyé sílẹ̀ láti gbé ìgbésẹ̀ tó ṣeé gbé kalẹ̀ àti ìdàgbàsókè nínú ìgbìmọ̀ náà lárugẹ. Nítorí èyí, Ìgbìmọ̀ Àgbáyé gbé ìgbésẹ̀ láti mú kí àwọn àwùjọ lágbára lọ́nà tó bá ìdájọ́ mu.

  1. Igbimo agbaye yoo maa to ajo Wikimedia Foundation sona lori awon akitiyan ikowojo lati le de oro fun irin ajo ipolongo wikimedia ni ibamu pelu awon ise ati iye re.
  2. Igbimo agbaye yoo fi alakale ti a n tele lole fun pipin awon owo ni dede lati le se atileyin fun awon ise Wikimedia, awujo, alamunlera, ibudo ati awon ajo iyipada miiran.
  3. Igbimo agbaye yii o ri daju wipe akoyawo wa ninu ipinnu sise, yi o pese itosona ati lilo ojuse alase lori irinkerindo egbe ipolongo kaa kiri
  4. Igbimo Agbaye yoo seda tabi tun igbimo alabesekele se fun isejoba gbogbo gbo alamunlera ati ibudo
  5. Igbimo agbaye yoo seda awon ikanni lati le je ki ati ri awon ohun elo (owo, eniyan, imo) gba rorun fun olodanni ati iro lagbara awon awujo ni ona aparo kan ko ga ju kan lo
  6. Igbimo agbaye yoo rii daju pe isiro wa pelu siseto awon ona a n gba ati ti s fi n jabo

Ojuse ati awon Agbara ti o ro mon

[Akiyesi: Awon agbara wonyi ni akiyesi ti o gbooro lati apero MCDC. Gbogbo won yoo beere yala ni kekere tabi afikun pataki alaye ti a ba se amunlo re. Awon ojuse lorisirisi ni akiyesi ti oro ofin WMF]

Gbigba awọn iṣẹ akanṣe ede tuntun - eto awọn ajohunše

  • Igbimo alabesekele ti ede (LangCom) n jabo fun igbimo agbaye. Igbimo Agbaye n se ipinnu ikehin lori foomu ati igbekale ti LangCom, labe awon ipese laarin ipolongo charter.
  • Igbimo Agbaye le se atunse awon ibeere pataki fun awon ise akanse ede je mimo tabi gba nimoran pada.
  • Igbimo Agbaye le yan lati gba LangCom laaye lati se idanimo taara awon ise akanse ede tuntun tabi ki o da ase yen duro fun ara re.
  • Ninu igbekale tuntun yii, LangCom ni a fun ni ise sise lati rii daju pe awon ise akanse ti a dabaa je pataki ti atileyin ti o to si wa fun.

Gbigba awọn iṣẹ akanṣe onibatan tuntun – nilo ifasilẹ

  • Igbimọ Agbaye ni ẹtọ lati fọwọsi awọn iṣẹ akanṣe onibatan tuntun eyikeyi fun ipolongo yii. Ipinnu naa yoo da lori iṣeduro ṣiṣeeṣe lati ọdọ Igbimọ onimo ero ati ifọwọsi lati ọdọ agbalejo iṣẹ akanṣe tuntun. Lọwọlọwọ WMF jẹ agbalejo fun gbogbo awọn iṣẹ akanṣe.
  • Igbimọ Agbaye yoo ṣe akiyesi imọ-ẹrọ ati awọn igbero ṣiṣeeṣe lati ọdọ Igbimọ Imọ-ẹrọ ati agbalejo ise akanse ati pe yoo tun ṣayẹwo boya iṣẹ akanṣe naa ṣe deede pẹlu awọn iye ipolongo yii. Igbimọ Agbaye yoo tun ṣayẹwo boya o ni atilẹyin to ni awọn ofin ti awọn olootu ti nṣiṣe lọwọ.
  • [Akiyesi: iru ojuṣe yii le jẹ atunṣe ni atẹle ẹda ti Agbofinro Iṣẹ akanṣe onibatan.]

Pipade ti awon ede ati ise agbese onibatan

  • Igbimo Agbaye ni ase lati dase awon ipinnu lati ti ise akanse ede kan. O le seto awon ilana tire lori boya lati dibo lori iru awon oran naa. Nibi ti ko ba ti dibo, igbimo alabesekele ede (LangCom) yoo se ipinnu naa
  • Idibo idaniloju ti igbimo agbaye ni a nilo lati tesiwaju pelu pipade ise akanse. Igbimo agbaye le seto ohun amuye ki a to dibo. Agbeyewo iseese ise akanse ti o n tesiwaju ati pataki pipade ni a o yewo finni finni ki a to se idibo ikehin nipase igbimo agbaye
  • Igbimo agbaye, nipase LangCom, yoo ni ase lati seto awon isedede lati tii ise akanse kan. Nibi ti ko si igbese igbimo agbaye, LangCom yoo tesiwaju lati seto awon isedede tire.

Igbimọ imọ ẹrọ

[Akiyesi si oluka: Igbimo imo-ero wa ni ijiroro ni kutukutu pupo. Bii iru bee, o je alaye ti o kere die ju awon igbero miiran lo ati pe yoo ni anfani pupo julo lati ironu ati esi agbegbe.]

  • Igbimo agbaye yoo sise pelu WMF eso ati imo-ero pelu awon ajo oludasi imo-ero lati seto igbimo imo-ero. Ipinnu ikehin lori igbekale ati akopo ti igbimo imo-ero yoo je nipase igbimo agbaye.
  • Igbimo imo-ero n jabo fun igbimo agbaye. O n sise bi afara laarin igbimo agbaye, WMF ati awon agbegbe imo-ero.
  • Igbimo imo-ero yoo ni ase apapo pelu:
    • Awon agbegbe ti idagbasoke imo-ero ti se pataki julo
    • Alakale Idagbasoke ti o gbooro lori bi a se le se awon eyi ti o se pataki julo
    • Ilosiwaju ilana fun apejo ati lilo awon esi lori idagbasoke imo-ero
  • Igbimo imo-ero yoo dabaa awon pataki re ati awon erongba si igbimo agbaye. Igbimo agbaye ni agbara lati fowosi tabi ki o ko awon erongba naa.

Idanimọ ati Iyokuro ti awọn alafaramo: ipilẹ-iṣapẹrẹ ati ṣiṣe ipinnu iṣakoso

  • Igbimo agbaye yoo se idanimo ati iyokuro awon alafaramo nipase igbimo kekere (Igbimo awon ibatan). O le seto tabi satunse awon ilana atele fun awon alafaramo lati tesiwaju fun idanimo ati lati gba awon ifunni. Awon ipilie ilana atele ni yoo je eyi ti fi bo ninu isori.
  • Igbimọ Awọn ibatan (AffCom) n jabọ si Igbimọ Agbaye. Igbimọ Agbaye n ṣe awọn ipinnu ikẹhin lori fọọmu ati igbekalẹ AffCom, lori awọn ipese ti igbimo Isin.
  • Igbimọ Agbaye le yan lati gba AffCom laaye lati da awọn alafaramo mọ taara tabi ki o da aṣẹ yẹn duro fun ararẹ.
  • Ninu igbekale tuntun yii, AffCom jẹ iṣẹ ṣiṣe lati rii daju pe awọn alafaramo n ṣe iranlọwọ awọn iṣẹ akanse sise.
  • Ni afikun, AffCom n se akojọ ati ayẹwo ẹri fun itako ti alafaramo, ati fifi awọn iṣeduro silẹ. Igbimo agbaye yoo gba tabi ki o ko awon nkan won yii.
  • Igbimọ Awọn alabojuto WMF ni idaduro agbara lati yọkuro awọn alafaramo fun ilokulo awọn aami-išowo, ofin, tabi awọn iṣe pajawiri. Ayafi ni awọn ipo pajawiri, won yoo wa adehun Igbimọ Agbaye ipinnu yii.
  • Awọn ẹ̀ka mẹ́ta lo wa: orí, àjọ tó ń gbeni ró ati awujọ àwọn oniṣe. Àwọn ẹ̀ka tuntun tó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ yóò wà fún Ìgbìmọ̀ Àgbáyé/AffCom, tí Ìgbìmọ̀ Àwọn Alátùn-únṣe WMF yóò sì fọwọ́ sí.

Idanimọ ati Iyokuro ti awọn alafaramo: ipilẹ-iṣapẹrẹ ati ṣiṣe ipinnu ibudo

  • Igbimọ Agbaye yoo ṣe abojuto iṣẹ ilọsiwaju ipolongo yii nipasẹ isọdọkan ti AffCom ati awon ibudo.
  • Ìgbìmọ̀ Àgbáyé ló máa ń bójú tó ojúlówó ojúṣe láti mọ àwọn ibi tí àwọn ilé ìtajà ti ń gbé.
  • AffCom’s scope is expanded to evaluate Hubs. The committee will be responsible for evidence-gathering and criteria review, and submit recommendations to the Global Council for recognition.
  • AffCom will be responsible to review the hubs’ functioning, capacity and assess evidence before submitting recommendations to the Global Council for derecognition of a hub.
  • WMF Board of Trustees retains the ability to de-recognise Hubs purely for misuse of trademarks or legally necessary actions. Except in urgent situations, the Global Council's agreement will be sought in this decision.
  • The Global Council works with both the Hubs and relevant teams within the WMF to enable cross-hub co-operation and, where necessary, mediation.

Affiliate & Hubs Advancement

  • The Global Council shall monitor the work of movement advancement through the coordination of AffCom and Hubs.
  • AffCom will primarily be responsible for guiding organisational development and ensuring adherence to good governance principles.

Fundraising

  • The Global Council will not raise funds in any way.
  • The Global Council, with support from the Wikimedia Foundation, will develop a policy that applies to all Movement entities around fundraising. This will include rules that can be adapted to local context and needs.
  • The Global Council and WMF will collaborate on processes to coordinate Movement fundraising.

Fund Dissemination

  • The Global Council will issue a recommendation to the WMF Board of Trustees with regards to the criteria for assigning the share of total central revenue to community general funds, regional fund committees, and any cross-regional grant dissemination.
  • Regional fund committees will report to the Global Council to demonstrate activity that is effective, equitable, and accountable.

;Open Questions regarding Fund Dissemination

  • What role should the Global Council have in fund dissemination?
    • Oversight or review of WMF decisions
    • Coordination with WMF
    • Other (please elaborate)
  • Should there be a committee that reports to the Global Council and handles central/cross-regional fund dissemination?
  • What should be the Global Council’s role with regards to the allocation of the funds within the WMF?
    • The Global Council should be consulted on the allocation of the funds within the WMF.
    • The Global Council should have no role in the allocation of the funds within the WMF and only be informed.
    • Other (please elaborate)

Global Site Policies - proposal retracted due to vetoing legal concerns

Summary of removed proposal: the Global Council would be a consulting partner on changes by the WMF to global policies. The Global Council can reject them unless they are legally mandated.

Reasoning leading to this proposal: during the pre-MCDC process, there was a desire for the Global Council to be able to reduce the frequency and scale of Communities/WMF disputes. The disputes happen for several reasons, and planned efforts to improve consultation and aspects such as the Technology Council should help with some areas. However, global policies and actions around them have caused past disputes, and the Movement Charter Drafting Committee felt this could prevent issues in this area in the future.

Summary of legal removal grounds: most WMF global policy actions are based on a risk evaluation/judgement call, not a brightline interpretation. There was also a concern that some policies are implemented to prevent more problematic legislation being created.

Request for: Alternative proposals that can mitigate, if not eliminate, major disputes between community and WMF regarding global site policies in the future.

User safety

  • The Global Council possesses an advisory role in assisting user safety, such as through aiding training and collaboration.
  • Formal authority continues to reside with the relevant body (local projects, Universal Code of Conduct Coordinating Committee (U4C), Trust & Safety, etc.).

Mediation

  • The Global Council will also hold a mediating role in cases where 2 or more entities are unable to resolve significant disagreements between them. The Global Council will act as a neutral party with a goal of assisting dispute resolution and/or mediation.

Structure

[Note to reader: there are scenarios for how to structure the Global Council that we will invite community to provide feedback on during the community consultation]

;Open Questions regarding Structure

  • Should the Global Council exist only as an executive body or should it exist as an executive body with an advisory board? (See scenarios below)
    • If the Global Council is an executive body with an advisory board, how are the members of both entities (executive body and advisory board) seated?
  • With its size, the Global Council must have adequate diversity and clout, but not be so large as to undermine effectiveness. As an executive body, how many members should the Global Council have?
    • Option 1: 9-13 members
    • Option 2: 17-21 members
A simple tree diagram showing the 2 scenarios described below.

Scenario 1: Global Council as an executive body

The Global Council executive body will be formed by two tranches, XX seats originally on “Tranche 1” and XX seats originally on “Tranche 2”.[1][2]

Example assuming a Global Council of 17 members; if the Global Council is a different size, the proportions would be kept, more or less.
Tranche 1 Tranche 2 Appointed
Number of Members 5 community-elected
3 affiliate-elected
5 community-elected
2 affiliate-elected
2 (1 of which must be a WMF employee)
Selection Process Community-elected seats are chosen in an open and community-wide election. Potentially with some limitations on excessive project presence.
Affiliate seats are chosen from the same candidate list, with each chapter/Thematic Organisation and a subset of user-groups receiving 1 vote.
Chosen by the elected Global Council members.
WMF to propose their representatives
Term of service Default of 2 year term. Exceptions apply for initial onboarding of Global Council and re-balancing of tranche sizing. Maximum and default of 2-year terms, Global Council may specify a shorter length to align with elections.
Representation/Purpose Members represent the Movement as a whole. Their purposes are those determined by the Global Council’s mission and the electorates’ needs and wishes. Primarily designed to provide specialised expertise and experience.
Example of a tranche system for a Global Council of 17 people
Tranche 2024 2025 2026 2027 2028 2029
1 5 members 5 members 5 members
2 5 members 5 members 5 members
1 3 members 3 members 3 members
2 2 members 2 members 2 members
1 member 1 member 1 member
1 member 1 member 1 member

                       


Scenario 2: Global Council as an executive body with an advisory board

The Global Council will have an advisory body; this advisory body will act as a consultation body for the Global Council, as well as community representation. This body will have between 70-100 members who are selected or elected.

;Scenario 2.1 Advisory Board & Global Council both follow elections
There will be selections or elections for both the advisory board and the Global Council executive board.
;Scenario 2.1.1
Two separate selections or elections: one for advisory board and one for the Global Council executive body.
;Scenario 2.1.2
One election or selection process, whereby the top 9-21 (depending on the range of seats available) candidates are seated in the Global Council executive body, and the following 70-100 members make up the advisory board.
;Scenario 2.2 Advisory Board selects Global Council executive body
The advisory body is selected/elected first, and then nominates 9-21 (depending on the range of seats available) members from within their group to serve as the Global Council executive body.

Membership

  • The Global Council core group will have a total of XX members [open question above].
    • 9-13 members
    • 17-21 members
  • Potential limitations on Global Council membership, including no limitations (see questions below).
  • The Global Council may permit up to 2 WMF or WMF Board of Trustees observing members with no voting rights. The Global Council may set appropriate conditions for these observer members.
  • Global Council members can be members of the reporting committees or subcommittees. However, if any committee or subcommittee reporting to the Global Council does not have a Global Council member, they should have a Global Council liaison.
  • All voting members will have 1 vote in any decision of the Global Council.
  • Members are to serve Wikimedia as a whole and are not serving as a representative of any sub-group, region, or entity within Wikimedia.
  • Each member serves 2-year terms.

;Open Questions regarding Membership

With an intention to ensure fair representation, power balance, and promote diversity and inclusivity within the Global Council, we seek your inputs on the following:

  1. Should there be some imposed limits to the membership in terms of movement representation?

Please share your opinions about potential criteria of such limits:

  1. Should there be a regional cap, e.g. max 3 persons from a single region? If yes, please specify the condition.
  2. Should there be a home project or entity cap, e.g. max 2 persons from a single wiki project or affiliate? If yes, please specify the condition.
  3. Should there be a specific cap for large[3] language communities, projects, or affiliates, e.g. not more than 5 seats from between the 5 largest projects? If yes, please specify the condition.
  4. Should there be any other limits for Global Council membership? If yes, please specify the condition.

Election Process

  • All nominations for each tranche’s election are made to a single candidacy list.
  • The community-elected members will be chosen at-large using a single transferable voting system.
  • Selected seats will be chosen by affiliates using a single transferable voting system, with each affiliate receiving 1 vote.
  • The top affiliate ranked candidates will be elected and removed from the candidacy list. Then, the top community-ranked candidates will be elected.
  • Eligibility standards for community voting will match the approved movement standards.

Candidate criteria & limitations

  • Candidates must meet the voter eligibility criteria for WMF Board of Trustees elections to file nomination
  • Candidates may be paid WMF, affiliate, or hub, staff/contractors but must clearly disclose this information at the beginning of the election
  • Members may not become paid staff during their term without resigning their position
  • Members may only serve four consecutive years (equivalent to two full terms) as a global council member. A period of six months is required for a member’s terms to not be consecutive.
  • Candidates must be in good community standing (meaning they are not currently suspended or otherwise prevented from participating).
  • Members are expected to consistently participate in the Global Council activities.
  • Members must be willing to sign and comply with the terms of appropriate private information policies, including a non-disclosure agreement.

Limitations and Safeguards

[To be written after further progress on powers and responsibilities, as the necessary level of limitations/safeguards will vary depending on these.]

Appendix

  1. Appendix (implementation): In the original election processes, the top 6 community-elected and top 3-affiliate elected members will receive 3 year terms on Tranche 1, with the remaining members receiving 2 year terms on Tranche 2. At the end of the second year, Tranche 2 will run an election, with members then receiving 2-year terms.
  2. Appendix (resignations): In the event of resignation (or other removal from position) during a term, that seat will be filled in the next election. If a shift would cause that Tranche’s size to grow to 9 members, then the new seat will be a full term. If a Tranche would grow to 10+ seats, then the bottom-ranked incoming members will receive 1-year terms.
  3. As determined by number of active editors for projects and voting members for affiliates

Further reading