Jump to content

Wikimedia Foundation elections/2021/2021-08-20/Board voter e-mail/yo

From Meta, a Wikimedia project coordination wiki
This page is a translated version of the page Wikimedia Foundation elections/2021/2021-08-20/Board voter e-mail and the translation is 90% complete.
Outdated translations are marked like this.

Kópa nínú ètò ìdìbò fún Àwọn Ìgbìmọ̀ Onígbòwó Wikimedia Foundation ti 2021

Olùfẹ́ $USERNAME,

À nké sí ọ torí wípé o ní àṣẹ láti dìbò nínú ètò ìdìbò fún Àwọn Ìgbìmọ̀ Onígbọ̀wọ́ Wikimedia Foundation ti 2021, tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀.

Wikimedia Foundation nṣiṣẹ́ lórí àwọn iṣẹ́-àkànṣe bíi $ACTIVEPROJECT pẹ̀lú ìdarí Ìgbìmọ̀ Onígbọ̀wọ́, gẹ́gẹ́ bí aláṣẹ Wikimedia Foundation. Kọ́ si nípa Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́.

L'ọ́dún yìí, a ó yan ìjókò mẹ́rin nípasẹ̀ ìdìbò àwọn ará. Àwọn olùdíje ogún káàkiri àgbáyé ni ó n díje fún àwọn ìjókò wọ̀nyí. Kọ́ si nípa àwọn olùdíje fún Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ ti 2021.

Ìdí nìyí tí à nbèrè fún ìwọ àti àwọn ará 70,000 káàkiri àgbáyé láti dìbò. Ìdìbò yí ó bẹ̀rẹ̀ ní 00.00 UTC 18 August títí dé 23:59 UTC 31 August. Láti dìbò, lọsí [$SERVER/wiki/Special:SecurePoll/vote/Wikimedia_Foundation_Board_Elections_2021 SecurePoll lórí $ACTIVEPROJECT].

Ka ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ lórí ìdìbò yìí.

Pẹ̀lú ìfọwọ́sí,

Ìgbìmọ̀ elétò ìdìbò


This mail has been sent to you as you have registered your email address with the Wikimedia Foundation. To remove yourself from future election notifications, please add your user name to the Wikimedia No Mail List.