Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ ti Wikimedia Foundation/Ìpè fún èrò: Ètò ìdìbò fún Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́/Àwọn Ìbéèrè Gbòógì
Discussion links to each question’s discussion are below. Please discuss the questions in those sections so everyone can see what is being discussed about the question. If conversations are happening elsewhere, please list them in the conversation table below.
Community members are encouraged to add proposed solutions to the questions. Please discuss solutions for a short time first and then propose the solutions and link them below each question. This way other community members may collaborate on the proposed solutions.
Àwọn Ìbéèrè
- Kíni ọ̀nà tó dára jùlọ láti rí dájú wípé ìsojú onírúurú wà láàrín àwọn ẹni tí a bá dìbò fún? (ṣe ìjíròrò ìbéèrè yìí)
Ìgbìmọ̀ Àwọn Onígbọ̀wọ́ kíyèsi pàtàkì fún àwọn olùdíje tó ṣ’ojú iye onírúurú ará àjọṣepọ̀ Wikimedia. Ètò tì si hìn ṣe ojú ìṣájú sí àẉon ará North America àti Europe. |
Àwọn ìgbèrò tó jọmọ́ ìbéèrè yìí
- Fi ìgbèrò re sí bí
- Establish a Global Council composed of members elected by regional districts
- Organise this year's affiliate selection by geographic area/constituency.
- Re-define the issue as "diversity of opinion" and not "geographic diversity".
- The Wikimedia Foundation should fund an independent Wikimedia Community Election Committee
- Kíni à nre tí lát’ọ̀dọ̀ àwọn olùdíje láàrin ètò ìdibò náà? (ṣe ìjíròrò ìbéèrè yìí)
Àwọn olùdíje Ìgbìmọ̀ ma n ṣe ìbẹ̀wẹ̀, àti dáhùn àwọn ìbéèrè àwọn ará tẹ́lẹ̀. Báwo ni ìdìbò ṣelè pèsè òye sínú ayé àwọn olùdíje tí yí ò sì mọ rírì wọn gẹ́gẹ́ bí olùfarajìn? |
Àwọn ìgbèrò tó jọmọ́ ìbéèrè yìí
- Fi ìgbèrò re sí bí
- How should affiliates participate in the elections? (ṣe ìjíròrò ìbéèrè yìí)
Two seats of the Board of Trustees due to be filled this year were filled in 2019 through the Affiliate-selected Board seats process. A change in the Bylaws removed the distinction between community and affiliate seats. How should affiliates be involved in the selection of new seats? |
Àwọn ìgbèrò tó jọmọ́ ìbéèrè yìí
- Fi ìgbèrò re sí bí
- Have a process determined by affiliates collectively. There is no good reason to exclude affiliates for two main reasons. Firstly, we have a significant decentralisation (regions, hubs) movement which affects mainly affiliates but almost not online communities. Secondly, affiliates were involved in the MCDC election just a few months ago, affiliates is almost the only one without strong English Wikipedia domination, thus removing this group would be disappointing diversity-wise. I think asking affiliates to come up with the (s)election process is the most sensible way to move forward — NickK (talk) 22:59, 16 February 2022 (UTC)
Other proposals
Àtòjọ àwọn ìjíròrò
This is a list of past, present, and proposed conversations organized in the context of the Call for feedback: Board of Trustees election. If you are organizing a conversation, please list it on this table.
Ọjọ́ | Orúkọ Iṣẹ́-àkànṣe | Ìtọ́kasí ìjíròrò | Olùṣètò | Àwọn Àkíyèsí |
---|---|---|---|---|
Nlọ-lọ́wọ́ | Meta-Wiki | Discuss the key questions | Movement Strategy and Governance team | Kọ ní èdè tó bá wù ọ́ |