Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí

From Meta, a Wikimedia project coordination wiki
Jump to navigation Jump to search
This page is a translated version of the page Universal Code of Conduct and the translation is 70% complete.
Outdated translations are marked like this.
Other languages:
Bahasa Indonesia • ‎Bahasa Melayu • ‎Basa Bali • ‎Deutsch • ‎English • ‎Esperanto • ‎Hausa • ‎Lëtzebuergesch • ‎Minangkabau • ‎Tiếng Việt • ‎Türkçe • ‎Yorùbá • ‎asturianu • ‎dansk • ‎eesti • ‎español • ‎français • ‎hrvatski • ‎italiano • ‎polski • ‎português • ‎português do Brasil • ‎suomi • ‎svenska • ‎vèneto • ‎Ελληνικά • ‎български • ‎русский • ‎српски / srpski • ‎українська • ‎العربية • ‎فارسی • ‎لۊری شومالی • ‎کوردی • ‎डोटेली • ‎नेपाली • ‎मैथिली • ‎हिन्दी • ‎বাংলা • ‎ગુજરાતી • ‎தமிழ் • ‎తెలుగు • ‎ไทย • ‎ქართული • ‎中文 • ‎日本語 • ‎한국어
Universal Code of Conduct

Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí (UCoC) pinnu láti ṣ'ètò ìpelẹ̀sẹ̀ iwà tí ó bójú mu fún àjọṣepọ̀ Wikimedia àti gbogbo àwọn ìdáwọ́lé rẹ̀ẹ̀

UCoC jẹ́ ìdásílẹ̀ ìlànà-ìṣe pàtàkì kan látori àwọn ìjíròrò ará àjọṣepọ̀ yìí àti èto strategy Wikimedia 2030. Àwọn ẹgbẹ́ strategy fi ìmọ̀ràn mẹ́ẹ̀wá síwájú láti máa darí àjọṣepọ̀ Wikimedia lọ̀sí ìran 2030 rẹ̀ẹ̀. Ọ̀kan lára àwọn ìmọ̀ràn yìí ni láti "Pèsè fún Ààbò àti Ìbániṣepọ̀," nípasẹ̀ kíkọ àlàkalẹ̀ fún Ìhùwàsí yìí. Àkójọpọ̀ UCoC yìí wáyé nípasẹ̀ àjùmọ̀ṣe gbogbo àwọn ẹgbẹ́ àjọṣepọ̀ Wikimedia, pẹ̀lú ọ̀wọ̀ fún àwọn òfin àti àlàkalẹ̀ tí ówà nílẹ̀, pẹ̀lú àwọn ìgbékalẹ̀ fún ìgbófinró àti píparí rògbòdìyàn. Alè rí àwọn ìjíròrò ará Wikimedia lórí àlàkalẹ̀ gbogboògbọ̀ fún Ìhùwàsí ló jú ìwé yìí.

Àjùmọ̀ṣe UCoC yìí nwáyé ní ipele méjì. "Ìpele àkọ́kọ́" tí ó wáyé láti oṣù keèfà títí dé oṣù kejìlá 2020 jẹ́ ìpele fún ìwádìí àti ìjíròrò pẹ̀lú àwọn ará Wikimedia lóri bí ó ṣe yẹ kí UCoC kó rí. Àbájáde ìpele yìí ni àlàkalẹ̀ UCoC yìí, tí yíò kan gbogbo iṣẹ́ tí ónwáyé nínú àjọṣepọ̀ Wikimedia. Ìgbìmọ̀ àwọn Onígbọ̀wọ́ Wikimedia ṣe ìkéde ìfọwọ́sí wọn sí àlàkalẹ̀ UCoC yìí ní 2 Fébúárì 2021. "Ìpele ìkejì" yíò dálé ìjíròrò àti kíkọ ìmọ̀ràn lóri bí ati lè gbé òfin UCoC ró. Ipele yìí bẹ̀rẹ̀ ní oṣù kejì 2021.


Láàárin 2018 àti 2020, ètò strategy Wikimedia 2030 pe àwọn olùfarajìn làti wo ìtọ́sọ́nà tí ó dára jù fún ọjọ́ iwájú àjọṣepọ̀ Wikimedia. Nípasẹ̀ àwọn ẹgbẹ́ iṣẹ́, ìjíròrò ayẹ́lujára, àti àpéjọ ojú-kojú kárí ayẹ́, akéde àwọn ìmọ̀ràn mẹ́ẹ̀wá àti àgbékalẹ̀ ní May 2020. Ọ̀kan lára àwọn ìmọ̀ràn yìí ni láti "Pèsè fún Ààbò àti Ìbániṣepọ̀".


Láàárin 2018 àti 2020, ètò strategy Wikimedia 2030 pe àwọn olùfarajìn làti wo ìtọ́sọ́nà tí ó dára jù fún ọjọ́ iwájú àjọṣepọ̀ Wikimedia. Nípasẹ̀ àwọn ẹgbẹ́ iṣẹ́, ìjíròrò ayẹ́lujára, àti àpéjọ ojú-kojú kárí ayẹ́, akéde àwọn ìmọ̀ràn mẹ́ẹ̀wá àti àgbékalẹ̀ ní May 2020. Ọ̀kan lára àwọn ìmọ̀ràn yìí ni láti "Pèsè fún Ààbò àti Ìbániṣepọ̀".

A ó fìdi àwọn òdiwọ̀n gbogboògbọ̀ múlẹ̀ fún àyíká ìbániṣepọ̀, ààbò, tí kọ̀sí ìyọlẹ́nu. Èyí yíò jẹ́ kí a lè fa ojú àwọn olùfarajìn titun mọ́ ra káà kiri, fún ìdàgbà só kè àjoṣepọ̀ Wikimedia.

Oùnkan gbòógì nínu àwọn ìmọ̀ràn yìí ni láti ṣẹ̀dá àlàkalẹ̀ fún Ìhùwàsí, UCoC. Àlàkalẹ̀ yìí pinnu láti ṣ'ètò "ìpelẹ̀sẹ̀ iwà tí ó bójú mu fún àjọṣepọ̀ Wikimedia, láìsí ìfàyègbà fún ìyọlẹ́nu". Àwọn ará Wikimedia má n siṣẹ́ ní oríṣiríṣi ìṣètò; kòsí àlàkalẹ̀ fún ìhùwàsí tí yíò kárí gbogbo ipọ̀ àti ọ̀rọ̀ àríyànjiyàn. Tí abá mú àwọn òfin iṣẹ́ de ojú-ìwọ̀n láti lo àlàkalẹ̀ yìí, àwọn olùkópa àti ìdáwọ́lé àjọṣepọ̀ Wikimedia yíò ní láti tẹ̀lé àti k'ọ́lé ìpelẹ̀sẹ̀ yìí tí UCoC yíó fìdí tì.

Gẹ́gẹ́ bí àlàyé Ìgbìmọ̀ àwọn Onígbọ̀wọ́ WMF ṣe sọ, iṣẹ́ UCoC yìí pín sín ipele méjì. Ìpele àkọ́kọ́ ("Phase 1) jẹ́ ìpele fún ìwádìí àti [[ìjíròrò pẹ̀lú àwọn ará Wikimedia, pẹ̀lú ẹgbẹ́ àpapọ̀ àwọn olùfarajìn àti òsìṣẹ́ tí wọ́n kọ ìlànà ìgbófinró UCoC. Wọ́n jọ̀wọ́ ọ̀rọ̀ inú ìlànà ìgbófinró yìí fun Ìgbìmọ̀ àwọn Onígbọ̀wọ́ WMF láti fọwọ́sí ní 13 October 2020. Ìgbìmọ̀ àwọn Onígbọ̀wọ́ Wikimedia ṣe ìkéde ìfọwọ́sí wọn sí àlàkalẹ̀ UCoC yìí ní 2 Fébúárì 2021.

The second phase ("Phase 2") of the project began on 2 February 2021, when the Board approved the draft UCoC text developed in Phase 1. The second phase of the project focuses on how to enforce the UCoC. As with the first phase, determining responsibilities and outlining clear enforcement pathways involves broad input from communities across the Wikimedia movement.

Current status

Content in this section is transcluded from the list of UCoC consultations. Please follow the timeline below for an overview of the UCoC process.

As part of Phase 2 of the process, there are multiple consultations with volunteers. The community consultations will inform the initial enforcement proposal draft and the draft before it is finalized.

Here is what is currently happening with the UCoC project:

Phase 2 of the UCoC project began with local language consultations. These were facilitated discussions with target language communities in discussion channels and platforms frequented by each of those communities. A comprehensive summary of these consultations was released in April 2021.

As our movement grows, community voices are needed to help shape the pathways to enforcing the UCoC that address the diverse needs of individual communities. The project team encourages communities to regularly share their experiences, ideas, and learnings with behavioral policies here on Meta, in consultations and discussions, or via email.

Ago-iṣẹ́

Ago-iṣẹ́ fún Ìpele Ìkejì àlàkalẹ̀ Gbogboògbọ̀ fún Ìhùwàsí
Ìṣẹ̀lẹ̀ Ọjọ́ Ipò
Ìwádì àwọn ìbéèrè ìgbófinró tí ó ṣe pàtàkì Ìgbìmọ̀ àwọn Onígbọ̀wọ́ WMF fọwọ́sí UCoC 2 Fébúárì 2021 Di síṣe
Àwọn àjùmọ̀ṣe-ìjíròrò fún ẹgbẹ́ ìbílẹ̀ (summary) Jánúárì-TBD Nlọ lọ́wọ́!
Àwọn àjùmọ̀ṣe-ìjíròrò fún àwọn ilé-iṣẹ́ Wikimedia Ìparí Fébúárì - March 2021 Ó nbò lọ́nà
Àwọn àjùmọ̀ṣe-ìjíròrò fún àwọn alámùójútó March 2021 Ó nbò lọ́nà
Àjùmọ̀ṣe-ìjíròrò fún Meta-wiki March 2021 Ó nbò lọ́nà
Ìjábọ̀ àwọn Ìfojúsìn fun Ìyọlẹ́nu April 2021 Ó nbò lọ́nà
Ìṣẹ̀dá àti fífọwọ́ sí ìmọ̀ràn fún ìgbófinró Call for participation: Phase 2 drafting committee Late March – April 2021 Open!
Ìgbìmọ̀ fún kíkọ: Àwọn ìmọ̀ràn fún ìlànà ìgbófinró April - Àárín May 2021 Ó nbò lọ́nà
Àjùmọ̀ṣe-ìjíròrò Meta-wiki fún àwọn ìmọ̀ràn ìlànà ìgbófinró Àárín May 2021 Ó nbò lọ́nà
Ìgbìmọ̀ fún kíkọ: Parí ìmọ̀ràn fún ìgbófinró June 2021 Ó nbò lọ́nà
Ìjọ̀wọ́ ìmọ̀ràn ìlànà ìgbófinró fun Ìgbìmọ̀ àwọn Onígbọ̀wọ́ ti WMF July 2021 Ó nbò lọ́nà
Ago-iṣẹ́ Ìpele àkọ́kọ́ ti Àlàkalẹ̀ Gbogboògbọ̀ fún Ìhùwàsí
Ìṣẹ̀lẹ̀ Ọjọ́ Ipò
Ìwáàdí àti ìponlongo ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀ ìkédèé àkópọ̀ àwọn àjùmọ̀ṣe-ìjíròrò fún ẹ̀dẹ̀ ìbílẹ̀ 15 June 2020 Di síṣe
Ìponlongo sí àwọn ilé-iṣẹ́ Wikimedia: Àwọn ìfimúfínlẹ̀ ati ìfọ̀rọ̀wánilẹ́nuwọ̀ June-July 2020 Di síṣe
ìparí ìponlongo sí àwọn ará Wikimedia pẹ̀lú ìkójọ àwọn èsì July 2020 Di síṣe
Ìparí àti ìkójọ àwọn ìfimúfínlẹ̀ fún àwọn òsìṣẹ́ Wikimedia Foundation July 2020 Di síṣe
Kíkọ Ìpè fún ìkópa: Ìgbìmọ̀ fún kíkọ: June 2020 Di síṣe
Yíyan ìgbìmọ̀ fún kíkọ 17 July 2020 Di síṣe
Ìgbìmọ̀ fún kíkọ: Ìpele kíkọ August-September 2020 Di síṣe
Àkókò àsọyé fún àlàkalẹ̀ UCOC tí a ti kọ September-October 2020 Di síṣe
Àtúnwò àlàkalẹ̀ UCOC lẹ̀yìn àwọn àsoyé ará Wikimedia 6-12 October 2020 Di síṣe
Ìjọ̀wọ́ àlàkalẹ̀ UCOC fun Ìgbìmọ̀ àwọn Onígbọ̀wọ́ WMF, pẹ̀lú ìtọ́ka sí àwọn àsoyé ará Wikimedia 13 October 2020 Di síṣe

Àwọn kókó tí ó ṣe pàtàkì: